Font Size
Johanu 1:1
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Johanu 1:1
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Ọ̀rọ̀ di ẹran-ara
1 (A)Ní àtètèkọ́ṣe ni Ọ̀rọ̀ wà, Ọ̀rọ̀ sì wà pẹ̀lú Ọlọ́run, Ọlọ́run sì ni Ọ̀rọ̀ náà.
Read full chapter
Johanu 8:58
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Johanu 8:58
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
58 (A)Jesu sì wí fún wọn pé, “Lóòótọ́ lóòótọ́ ni mo wí fún yín, kí Abrahamu tó wà, èmi ti wa.”
Read full chapter
Filipi 2:6
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Filipi 2:6
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
6 Ẹni tí, bí o tilẹ̀ jẹ́ ìrísí Ọlọ́run,
kò kà á sí ohun tí ìbá fi ìwọra gbámú láti bá Ọlọ́run dọ́gba.
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn (BYO)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.