Font Size
Òwe 20:22
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Òwe 20:22
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
22 Má ṣe wí pé, “N ó ṣẹ̀san àṣìṣe rẹ yìí fún ọ”
Dúró de Olúwa yóò sì gbà ọ́ là.
2 Kọrinti 8:21
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
2 Kọrinti 8:21
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
21 Àwa ń gbèrò ohun rere, kì í ṣe níwájú Olúwa nìkan, ṣùgbọ́n níwájú ènìyàn pẹ̀lú.
Read full chapter
1 Tẹsalonika 5:15
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
1 Tẹsalonika 5:15
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
15 (A)Ẹ rí i pé kò sí ẹni tí ó fi búburú san búburú, ṣùgbọ́n ẹ máa lépa èyí tí í ṣe rere láàrín ara yín àti sí ènìyàn gbogbo.
Read full chapter
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn (BYO)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.