Font Size
Ìṣe àwọn Aposteli 1:14
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Ìṣe àwọn Aposteli 1:14
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
14 Gbogbo àwọn wọ̀nyí pẹ̀lú àwọn obìnrin àti Maria ìyá Jesu àti àwọn arákùnrin rẹ̀ fi ọkàn kan dúró láti máa gbàdúrà.
Read full chapter
Romu 5:2
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Romu 5:2
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
2 (A)Nípasẹ̀ ẹni tí àwa sì ti rí ọ̀nà gbà nípa ìgbàgbọ́ sí inú oore-ọ̀fẹ́ yìí nínú èyí tí àwa gbé dúró. Àwa sì ń yọ̀ nínú ìrètí ògo Ọlọ́run.
Read full chapter
1 Tẹsalonika 5:17
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
1 Tẹsalonika 5:17
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
17 (A)Ẹ máa gbàdúrà nígbà gbogbo
Read full chapter
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn (BYO)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.